Jump to content

Gregory Agboneni

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gregory Agboneni
Administrator of Adamawa State
In office
9 December 1993 – 14 September 1994
AsíwájúAbubakar Saleh Michika
Arọ́pòMustapha Ismail
Administrator of Cross River State
In office
14 September 1994 – 22 August 1996
AsíwájúIbrahim Kefas
Arọ́pòUmar Farouk Ahmed

Gregory Agboneni jẹ́ ọmọ ológun ilẹ̀ Nàìjíríà tó ti fẹ̀yìntì tí ó di Alámojútó Ológun fún Ìpínlẹ̀ Adamawa àti Ìpínlẹ̀ Cross River láàárín Oṣù Kejìlá ọdún 1993 àti Oṣù Kẹjọ ọdún 1996 nígbà ìjọba ológun Ògágun Sani Abacha.[1]


  1. ↑ "Nigerian States". WorldStatesmen. Retrieved 2010-01-01.