Jump to content

Kano

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kano
Kano seen from Dala Hill
Kano seen from Dala Hill
StateKano State
Government
 • GovernorIbrahim Shekarau (ANPP)
Population
 (2007)
 • Total3,848,885
 estimated [1]
Time zoneUTC+1 (CET)
 • Summer (DST)UTC+1 (CEST)

KanoLL-Q34311 (yor)-AashaKhan1410-Kano.wav , jẹ́ olú ìlú Ìpínlè Kano àti ìlú tí ó tóbijùlo ẹ̀kẹta ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lẹ́yìn ìlú Ìbàdàn àti ìlú Èkó. Gẹ́gẹ́ bí ìkànìyàn ọdún 2006, Kano jẹ́ ìpínlẹ̀ tí ó ní èrò jùlọ ní orílẹ̀̀ èdè Nàìjíríà. Àwọn ibi tó lajú níbẹ̀ gba ìlẹ̀ tó tóbi tó 137 km2 tí ó sì ní àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́fà — Kano Municipal, Fagge, Dala, Gwale, Tarauni àti Nasarawa — pẹ̀lú olùgbélú 2,163,225 ní ìkànìyàn ọdún 2006.

Ìwé àkàsíwájú

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ↑ ""The World Gazetteer"". Archived from the original on 2012-12-08. Retrieved 2007-04-06.